Posts

MO NI OHUN TI MO FE SE NI OJO IWAJU NKO LE YA TATUU......REMINISCE

MO MA PADA SE ORIN LATI MU ILERI OLAMIDE SE........ELDEE THE DON.

NKO PADANU ETO IDIBO TO KOJA AWON OMO EGBE MI NI WON NI KIN MAI TI GBE GBA IBO.......

ARA MI TI MO KUN DAADA......PETER OKOYE

WIZKID ATI DAMMY KRANE NI ILE OBAFEMI MARTINS.....