Alara ni o lara, ohun ti o ba wu oni kalaku ni o le se pelu ara e, sugbon o emi pelu ohun ti awon olorin egbe
mi di asa emi ko le se, iyen taatu yi ya, eleyi ni olorin REMILEKUN ABDULKALID SAFARU ti gbogbo eniyan mo si REMINISCE so fun wa wipe ohun ni nkan ti ohun si ma se ni ojo iwaju.
Comments