Leyin osu meji si igba ti a wa yi ni ogbeni LANRE DABIRI ti gbogbo eniyan mo si ELDEE THE DON, kede wipe ohun ti feyiin ti ni idi ise orin yii, leyin na ni gbaju gbaja olorin OLAMIDE ti gbogbo eyan ma si
BADDOO, so wipe ohun ma feran lati ba ELDEE se orin po, elyi je iya lenu fun wa, nigbati iroyin yii to wa leti, se eniyan a ma lohun fe jeun ki o tun so wipe ohun o je mo.
Comments