WIZKID ATI DAMMY KRANE NI ILE OBAFEMI MARTINS.....

               
Bi ojo die si igba ti a wa yi ni agbo wipe dammy krane ati wizkid wo iya ija ni ibi ayeye ti agbabolu fun iko super eagles obafemi martins se ni ile igbafe ti quilox, ti won de tun fi to wa leti wipe obafemi martins ti pe
awon mejeji gege bi agbalagba lati pari ija na.

Comments