Awon agba bo won ni ibi ti erin meji ba ti ja koriko ibe kii tu gberi mo, ohun ni o di fa fun awon gbaju gbaja olori ile ise awo orin mejeji won yii eyi ti OLAMIDE(YBNL) ati ti DONJAZZY(SMD), nibi ti won ti fii ami eye da awon olorin igbalode ni ola, ohun ti o fa ija na ni wipe won fun REEKADOBANKS eyi ti o je omo egbe SMD ni amii eye olorin asiko to yanranti julo, eyi ti o si je wipe LILKESH omo egbe YBNL ni awon
eniyan ro kan si sugbon ti awon alabojuto ami eye ohun si fin ye wa wipe ohun (reekadobanks) ni awon eniyan dibo fun,nigba ti won kede wipe Reekadobanks ni o gba amii eye yi ohun ni o mu ki olori egbe ti YBNL Olamide jade lati fi okan re han si won wipe, inu ohun ko dun si nitori ohun ri wipe madaru ti wa ni be, o tun fi kun wipe ti aba ni ki a ma ka ni ese se orin ti awon meje ji ti se ti o gbodekan julo ohun na ni orin LILKESH beere lati ori "lyrically","shoki", ati efejoku ko si eyi ti awon eniyan gba ti e.
Comments