Yoruba ni, eni ti o so’wo ale’ yo le’ni (mat). O
wa bimi wipe, elo ni won ta eni gann ni ile yoruba?? Nibi ti eni gbo’po de ni
aye atijo, Yoruba a ma fi eni se ebun (gifts) fun awon Ara, Ore ati Ojulumo.
Eni ko ni Yoruba nso, Jesu gan so wipe, lowe-lowe loro mi. Awon omo Yibo ati
Awusa ti e ti so da’sa, won a ni ‘’Haa! Yoruba! agbere won ti poju!’’.
E je ka bi ara wa lere, nje ‘Owo Ale’ wa lara asa
(culture) yoruba bi?? Rara o, ko si ibi ti ‘Iwa ati Ise’ o si ni gbogbo agbala
aye, kooda, Bibeli ati Kurani gan soro nipa Owo Ale. Nigbati awa ni ile eko
giga Unifasiti, a ti e ma n gba ladura wipe, ki awon Ijoba agunbaniro (NYSC)
gbe wa lo si ‘Ila orun’ (East) lati lo sin ijoba. Kini idi adura wa? a mo
dajudaju wipe ibe ni Owo Ale pin si ni, kooda, ko ti e se pataki ko le’ni (it
is of need to have mat).
Ti Yooba ba so wipe, eni ti o so’wo ale, yo
le’ni, Ikilo pataki ni fun awon odo ati loko-laya . Bi won baani, ‘omode o kin
joko lori odo (mortal), ki see Eewo, ikilo imo tooto ni, nitori omode le fi
aibikita ya igbe si ori odo. Bee sini ti won ba so wipe, ‘omode o kin je epon
ewure’ kosi nkan ti epon ewure o fi omode se, Yooba fe de’kun iwa wonbiliki
wobia ni o.
Eko po ninu Asa Yoruba, melo la fe ka ninu eyin
adipele
Comments