L'ORI OKE ATI PETELE
IBE L'A GBE BI MI SI 0
IBE LA GBE TO MI D'AGBA O
ILE OMINIRA;
EMI O F' ABEOKUTA S'OGO
N O DURO L'ORI OLUMO
MAYO L' ORUKO EGBA 0
EMI OMO LISABI
MAYO! MAY0!! MAYO 0O
L'ORI OLUMO
MAYO! MAYO!! MAYO 00
L'ORI OLUMO
ABEOKUTA ILU EGBA
NKO NI GBAGBE RE,
NG 0 GBE 0 L'OKE OKAN MI
BI ILU ODO OYA;
EMI 0 MA YO L'ORI OLUMO
EMI 0 S'OGO YI L'OKAN MI
WIPE ILU OLOKIKI 0,
L'AWON EGBA NGBE.
CHORUS:
MAYO! MAYO!! MAYO O.
Egba Omo Lisabi, Omo Ajo Gberu Majo Gbeko, Eru Ni Nsini Eko Kin Nsiyan
Edumare Bawa Da Ilu Egba Si
Ase
Comments