Ati gbo orisirisi nipa iya yi wipe o n'gba itoju lowo ni ile-iwosan kan,eni ti o wa papo da ni ojo keje osu kefa odun ti awa wa ninu re yii,eni ti o ti je oga agba fun ile-ise ijoba ti NAFDAC rii,ati minisita fun iroyin ni orile ede ti awa yii,won gbe jade kuro ninu ilu yii losi ilu india lati lo fun i itoju ti o peye sugbon epa o boro mo,eni ti o je omo odun mokandinlogota,ki olorun bawa te si afefe rere.
Comments