ODUN OLOJO TI ILE-IFE

odun olojo je odun pataki yaato si odun osun-osogbo ti won se ni osogbo, ni ojo yii ooni ti ife yio fi ara han fun awon eniyan leyin opo irubo ati adura fun gbogbo ara ilu,pelu awon olorisa tooku,
okan lara awon olori oba yi o mu igbale lati gba ibi dannu ni afin oba,ooni ife yi o wa jade si awon eniyan pelu ade oduduwa gangan ti won si ma tesiwaju lati malo si ojubo ti OGUN,leyin eleyi oba ati awon oloye ati awon alawo ilu sugbon araba ti ile-ife ni o ma si waju lati losi ojubo okemogun, nibi ti won ti ma se adura ati irubo ni idi oosa yii ti gbogbo oloye oba yio ti mu ida ti a fi igi se ti a si kun ni efun.

ti gbogbo ilu yio ti ma beere fun ohun gbo ti won fe pelu igbagbo, hmmmm ISESE NI ASA-ASA NI ISESE.

Comments