ITAN OBATALA

Obatala je iranse eledumare,eni ti o gbe ere awon eniyan ti olorun si fi emi re si inu wa,oba funfun igbakeji olodumare, eni ti olodumare fi se olori gbogbo eda ti o da si aye lati fi ona han awa omo adamo,gege bi awon oni imo won ni obatala je egbon fun oodua,olodumare fun obatala ni agbara lati pa ati lati ji eniyan,

ti aba ma ki obatala ama wipe "OLUWA AIYE,ALABALASE,BABA ARUGBO,BABA ARAYE,ORISHANLA,OBATALA OBA TA SA OBA TAKUN-TAKUN  NI ODE IRANJE,
Obatala je oosa ti won mo kaakiri agbalaye,paapa ni ilu brazil.


Comments