ITAN ITAPA EKITI.


ITAPA je ilu kan pataki ni ipinle ekiti,ti o se wa lati odufuwa ti owatapa si je olori, itapa je oosa kan ti won bo ni ile-ife,o je odun ti won ma 'n se fun ogbon ojo ti ooni ife fun ra re ma n'bo tit doni,oodun yi ni won pe ni utaale ni ilu itapa.

Amowa ati elepe ti won je omo bibi inu oodua fi ile ife sile pelu iya won ti won si mu awon ore won meji daani,ELEMO ati BAARO ti won je ode igbo.
nigba kan ni elepe lo tedo si apa kan ninu oko itapa ti won pe ni OSIN,beena ni amowa na lo tedo si apa kan ninu oko itapa ti won pe ni IJELU TI OSI PADA DI ELEJELU.amowa ni o koko di olosin ti ilu osin.
 Ilu itapa ni oni ti di ilu nla ti
    OBA(DR)MAKANJUOLA D. AJAJA OLUFEMILOYE OLA (111),

Comments