ILE IRUN SISE TI IGBALODE NI ABEOKUTA.

Oge sise je ohun pataki ninu asa ati ise omo oodua,sugbon baye se n lo ni a n'to, aye ti di aye olaju awon omo obinrin wa o si di irun adi mole mo, irun ti oloyinbo lorisirisi ni won se ni si yin,pelu oruko orisirisi,won ni ti ayeban yi ki ama ba won yi, ti a ba n'wa soro nipa irun igbalode sise "GLITTERS BEAUTY ARCADE"



eyi ti o kale si ilu abeokuta awon ni oluwa fi ran, danwo lo bi iya okere,panseke ni mercy road ni won wa fun iwadi elepe si ori ero ibanisoro yi 08063150560 tabi ero alateranse ti BB PIN:25D05A68.


Comments