AKONI TI ILU IKENNE REMO.

Ti a ba n'soro nipa akoni, a n soro koni okunrin ti ko beru enikan,afi olorun ti oda si aye, ti o si ko iyan awon eniyan kere,ti o se fun omode ati agba,ti o nwairorun fun gbogboawon eniyan ti o sun mo, eni ti oje ajija gbara fun gbogbo mekunnu, iru eni ti a n'so yi no ojogbon "AUGUSTUS TAIWO SOLARIN" eni ti a mo si TAI SOLARIN,eni ti abi ni ogunjo osu kejo odun 1922, ni ilu ikenne- remo ni ipinle ogun. o lo si ile iwe alakobere ati ti girama ni wesley college ni ilu ibadan,o tun tesiwaju lati lo darapo mo awon jagunjagun ti
ofurufu ni igba ogun ti agbaye keji, won si tesiwaju ninu eko won ni unifersiti manchester pelu ami to yaranti ninu imo itan ati ti geography. o tun tesiwaju ninu eko unifersiti ti ilu london,ojogbon tai solarin se igbeyawo pelu iyawo re "SHEILA MARY TUER" ni odun 1951 ti osi bi okunrin ati obinrin fun.
Tai solarin bi won se n npe,je enikan ti o ti ja takuntakun fun orile ede wa, lati gba ominira,ti o si je agbenu so fun gbogbo mekunnu,eleyi wa si imuse pelu ati leyin awon eniyan nla lori ile ede yi, tai solarin se iwe ti a pe akole e ni 'ibere ati opin"[begining and the end] eleyi ti o se okunfa bi awon ologun se ran lo si ewon.
 ojogbon tai solarin je omowe ti ko se figa gbaga pelu,ti o si mu ise re ni okunkundun, iko we re sori paper lo bi awon olori ogun ninu ti won fi so si ewon,ti ko si faramo ijoba awon ologun lori le ede yi, ti o si pinu lati fi iwa ibaje won han si agbaye, aso wiowo re koju sokoto penpe ati khaki lai gbagbe salubata re pelu fila oyinbo.
 Ni odun 1956 ni ogbe ile eko tie losi ilu ikenne, ti o si ti di ilu mooka kaakiri agbaye iyen "MAYFLOWER SCHOOL"Eyi ti o wa ni ilu ikenne ni ilu ti a ti bii, ile iwe ti bi opolopo olori ati olorire ni ori ile ede yii ti won si n se daada, sugbo ki o to ko ile eko ti e yi oti koko je oluko agba ile iwe "MOLUSI" ni ijebu igbo.
  Hmmmmmm, didun bayi ni iranti olododo, eje ki a se daada ki won le so nipa tiwa pe a se iwon ti a lese.

Comments