1-Ení or ookan, okan, ọ̀kan (for numismatics or currencies like cowries or coins).
2-È jì or Eéji (for numismatics or currencies like cowries or coins).
3-Ẹta or ẹẹ́ta (for numismatics or currencies like cowries or coins, same pattern till 19).
4-Ẹrin, ẹ̀rin or ẹẹ́rin
5-Àrún or aárùn
6-Ẹfà or ẹẹ́fà
7-Èje or eéje
8-Ẹjọ, ẹ̀jọ or ẹẹ́jọ
9-Ẹsan, ẹ̀sán or ẹẹ́sàn
10-Ẹwa,ẹ̀wá or ẹẹ́wà
11-Ọkanla, ọ̀kanlá, oókànlá
12-Ejila, èjìlá, eéjìlá
13-Ẹtala, ẹ̀talá, ẹẹ́talá
14-Ẹrinla, ẹ̀rinlá, ẹẹ́rìnlá
15-Ẹdogun (Ẹedogun, ẹ́ẹdógún)
16-Ẹrindinlogun, ẹẹ́rìndílógún
17-Ẹtadinlogun, eétàdílógún
18-Ejindinlogun, eéjìdílógún
19-Ọkandinlogun, oókàndílógún
20-Ogun, ogún, okòó or Okowo (ọkẹ owo for numismatics or currencies like cowries or coins).
21-Ọkanlelogun
22-Ejilelogun
23-Ẹtalelogun
24-Ẹrinlelogun
25-Ẹdọgbọn, ẹ́ẹdọ́gbọ̀n
26-Ẹrindinlọgbọn
27-Ẹtadinlọgbọn
28-Ejidinlọgbọn
29-Ọkandinlọgbọn
30-Ọgbọn, ọgbọ̀n, ọɡbọ̀n ǒ or Ọgbọnwo (Ọgbọn owo for numismatics or currencies like cowries or coins )
31-Ọkanlelọgbọn
32-Ejilelọgbọn
33-Ẹtalelọgbọn
34-Ẹrinlelọgbọn
35-Arundinlogoji, aárùndílogójì
36-Ẹrindinlogoji
37-Ẹtadinlogoji
38-Ejidinlogoji
39-Ọkandinlogoji
40-Ogoji, ogójì, ojì (Ooji, Ogun meji, two twenties)
41-Ọkanlelogoji
42-Ejilelogoji
43-Ẹtalelogoji
44-Ẹrinlelogoji
45-Arundinladọta
46-Ẹrindinladọta
47-Ẹtadinladọta
48-Ejidinladọta
49-Ọkandinladọta
50-Adọta (aadọta), àádọ́ta
51-Ọkanleladọta
52-Ejileladọta
53-Ẹtaleladọta
54-Ẹrinleladọta
55-Arundinlọgọta
56-Ẹrindinlọgọta
57-Ẹtadinlọgọta
58-Ejidinlọgọta
59-Ọkandinlọgọta
60-Ọgọta, ọgọ́ta, ọta (ogun mẹta, three twenties)
61-Ọkanlelọgọta
62-Ejilelọgọta
63-Ẹtalelọgọta
64-Ẹrinlelọgọta
65-Arundiladọrin
70-Adọrin (Aadọrin), àádọ́rin
71-Ọkanleladọrin
72-Ejileladọrin
73-Ẹtaleladọrin
74-Ẹrinleladọrin
75-Arundilọgọrin
76-Ẹrindilọgọrin
77-Ẹtadilọgọrin
78-Ejidilọgọrin
79-Ọkandilọgọrin
80-Ọgọrin (Ogun mẹrin, four twenties), ọgọ́rin, ọrin
81-Ọkanlelọgọrin
82-Ejilelọgọrin
83-Ẹtalelọgọrin
84-Ẹrinlelọgọrin
85-Arundiladọrun
86-Ẹrindiladọrun
87-Ẹtadiladọrun
88-Ejidiladọrun
89-Ọkandiladọrun
90-Adọrun (Aadọrun), àádọ́rùn
91-Ọkanleladọrun
92-Ejileladọrun
93-Ẹtaleladọrun
94-Ẹrinleladọrun
95-Arundilọgọrun
96-Ẹrindilọgọrun
97-Ẹtadilọgọrun
98-Ejidilọgọrun
99-Ọkandilọgọrun
100-Ọgọrun (ogun marun, five twenties), ọgọ́rùn, ọrún
Comments