NJE IWO TI LE MO OLORIN IGBALODE TI O NI IGBA?

Oluwaseun ariyo ati adeniyi ariyo,awon omo kunrin meji yii,ti egbon ti aburo bii ibeji, ti awon eniyan mo si EL-PHLEX,Ni won nigba lowo lowo ni agbo ile orinigbalode ti saa ti awa yi, ti won ti se awon orin pelu opolopo olorin igbalode bii reminisce,skale,sheyman,patorankin ati bebe lo, ti won si ti se awon orin bii
AMEN,LET'S GO THERE,GBETIWA,IN THE MOOD,JEAMALO,HOME AND AWAY,SHUT IT DOWN,ROGO, Ti awon oludari orin ilu moka se fun won bii SAUCE KID, T-IZZE,SHEYMAN,MASTER KRAFT ati bebelo ,Sugbon nje eti rigbo pe orin kan bo lona ti won pe ni LOW WAIST orin yii je orin ti odun gan ti e ma gbadun lati agbo ile orin PILLARS RECORD.

Comments