Oranyan,baba yoruba,omo bibi inu odudwa,Alaafin akoko ni ile oyo ni odun 1170,eni ti o wa lati ile- ife, ti o si wa te ile oyo do,ti omo ti ohun na tun wa bi di oba akoko ni ile benin, jagun jagun ti o jagun ile oyo sugbon nigbati o fe lo si oju ogun, o fi omo e si le pe ki o ma se oju ohun,sugbon leyin odun die won ko ri ki oranyan wa le,awon pe birikoto lati fi omo re joba ile oyo, inu re o dun wipe won o duro ki ohun fi de,ni idi eyi o tesiwaju lati pada si ile-ife, ti owa titi o fi pa po da, ti won si mu opa re fi se iranti re di eni.
Comments