ITAN FELA ANIKULAPO KUTI


Um um um…………..kini afi le se apejuwe ara kunrin yii,akikanju,okunrin ogun, olori,ajafeto makunu, abi si ilu Abeokuta ni ojo karundilogun osu kewa odun 1938,eni ti oje ajija gbara fun awonodo,eni ti ko fi gba kan gba tawon olori rara awon ati iwa ibaje ,eni ti abi si agbole oni gbagbo,eni ti a ran lo si ilu oyinbo lati lo ko nipa imo ogun oyinbo,ti osi lo yan orin kiko ni ayo,odarapo mo won ni trinity college of music ni odun 1958.

    Ti aba n peri akoni a fida hale garage,ta ni eni ti mon soro e yii ohun naa ni olufela,oludotun,olusegun,ransome kuti,ofe iyao re akoko ni odun 1960 iyen remilekun taylor ti oje iya femi,yeniati sola ni odun 1963 ni obi omo alakokore,o da egbe ti e si ile ni ilu oyinbo ti o pen i koola lobitos,fela fe iyawo metadinlogbon gbogbo won ni fela gbe ni iyawo ni ojo kan na,fela ko nipa oro siso ni  ori ero asoro magbesi iyen radio fun awon egbe soro soro ni orile ede naijiria ,osi man korin pelu awon olorin miran nigbana bii victor olaiya ati awon elegbe re to ku .
Ni odun1967 ogbe ra lo si ilu ghanalati lo ko ni pa imo orin si,ose orin kan nigbana ti ope akole re ni afrobeat ni odun 1967,fela ko awon omo egbe re lo si ilu oyinbo(united state) ti won lo osu mewa ni los angeles. nigbana ni o se awari oruko kan ti o peni agbara dudu(black power) nipase Sandra smith,oda oruko yi sile ni odun 1970,fela ati  awon omo egbe re wan i ilu oyinbo laisi ase itesiwaju ise lati owo ijoba.egbe yi sare se awo orin kan nigbati won wan i los angeles. fela je omo odun mejidinlogota ki oto papo da ni ojo keji osu kejo odun 1997 leyin aisan ranpe fun ose di e,okan ninu awon aburo re je ki o ye w ape aisa ko gbo o gun lose ku pa (AIDS) ati wipe otun ni arun ti okan. Iya re se takuntakun  nigba ija fun ominira orile ede yii, gbogbo olowo,olola ati mekunu ,eni ti o je wipe oja feto ilu titiwon ran lo si ewon nigbana ni won tun ran awon oloogun losi ile re iyen (kalakuta building) ni odun 1977,nigbati awon oloogun yii de ile re won ba iya re, abiamo ku oro omo won ju lati oke alaja mejilelogoji lati oju ferese si ile, ti o si farapa yana yana ti o da lapa ati ese, won dana sun ile re tiwon si palase pe ki awon pana pana ma de ibe,at gbogbo agbala ti o ti korin pelu awon awo orin re,ati awon elo orin re ni ojona sugbon sibe ko jawo ninu oro awon oloselu yii ko si dawo orin duro ,ko si ye ja feto mekunu,kini atu le so nipa eni rere,won ni didun didun ni iranti olododo.BABA FELA,BABA 70 SI WA BII AWON OLOYINBO WAN NI (FELA LIVES

Comments