ILE-IWE TI A N SAN MILIONU KAN NAIRA FUN

Eleyi ni ile iwe Madonna, ti opolopo obi n ti raka lati ran omo lo,ewo bi ile iwe na se da,ni bo ni owow ti won san lo, abi ama sowipe owo ti won san ni ko to ni abi kinni,ti awon omo ama beru lati lo se igbonse
ati lati we wa di isoro,
Ha ha, e ti se eyin ijoba eba wa da si eleyi  ema je ki iya yi gbe, pelu itara ni okan lara awon omo ile iwe yi fi ko eleyi fi sewo si ile ise wa ni owuro yi,ejo eba wa wa n kan se si, eleyi ku di e kato.

Comments