FATAI ROLLING DOLLAR

Hmmn,ti a ba n peri akoni ki a fida hale garaga,eni ti abi ni ojo kejilelogun osu keje odun1926 si ilu EDE, ni ipinle osun.
 Obere ise orin ni odun 1953,osi ko awon ogbontarigi olorin bii,
Ebenezer obey,Orlando owoh,bob aladeniyi ati bebe lo ni se, oje okan lara awon ti o da ere juju sile ni orile-ede yii.Tani eni ti mo'n soro e yi ohun na niFATAI OLAGUNJU OLAYIWOLA eni ti gbogbo eniyan mo si rolling dollar. Ni odun melo kan seyin awon eniyan ro wipe ojo ti lo fun baba lati ma ko orin bi tatijo, sugbon baba jo won loju pelu awo orin ti omode ati agba man ko ni gbogbo igba 'WON KERE SI NOMBA WA'koda won tun fi orin na se ipolowo oja bii ose dun to leti awon omo duniyan,gege bi ati se mo wipe baba feran awon omode pupo won bii omo merindinlogun, won fe omo binrin elere ori itage ti a mo si BUNMI AKINBO GOLD, leyin igba ti iyawo re akoko se alaisi ni odun 1999, ni otu se alaba pade awon ara binrin meji kan,ikan wa lati oke okun iyen (germany),ikeji si wa lati ilu ibadan.
  Baba je akinkanju,okunrin mewa,okunrin wa-wa-wo-wo,eja nla ninu ibu,okunrin ogun ti ko se koju ija si eni ti oje omo odun merindinladorin ti o n se bi omo ogun odun,iku ba la le jo ni ojo kejila osu kefa odun 2013,oma se ooo,odi gbere oda ri na ko odo ju ala,ohun ti won je ni ko bawon je lorun,iru tire sowon, looto ni won kere si nomba joor.

Comments