AWON ELERE ORI ITAGE TI O NI IGBA.

Eni ti o se ipo kinni ni odunlade adekola je osere ori itage ti o nigba lowo ti osi pegede ami eye ti yoruba movie academy award tio odun yi,ti o se awon ere ori itage bi mufu olosa oko,emi ni ire kan ati
awon ere to ku bebe lo.
Eni ti o se ipo keji na ni eni ti a mo bi eni mowo, ohun na ni obinrin bi okunrin ara binrin fathia balogun, se ti ara ti ko legbe lori ere oritage ni afe so ni abi, awon ere akomo logbon ti o man gbe jade, nje atie tun mo pe fathia balogun ti gbe ere agbelewo tuntun jade ti o pe ni torera,ti aba ti wo eleyi eje ki a lo ra ki a ko ogbon ni nu re.




Comments