Olorun ti se tan lati gbe ija awa omo naijiria ja, ni ojo keta osu yii ni a gbo wipe won tun ti se awari ile awon agbani pa kan ni ipinle Ogun Abeokuta ni Akinremi Estate ni Adigbe.
Ni ojo ojoru,ni won ri ara birin ti o sare jade ninu ile oloke meji yii, ti o si so gbogbo pohun ti o nsele ni inu ile yii fun awon ti o gbe ni agbegbe yii,ti o si se alaye pe ohun wa lati ilu abia state,wipe won ta ohun ni egbee lana ogorun naira (100,000 naira), ni won ta ohun fun awon apani yii.
ni ojo ojobo, ni awon odo adugbo na fon si ta lati lo ba ibe na je paapa awon akeeko ti poli moshood abiola(ojere), ti won si ba orisirsi nkan ni be bii,ogun,igba ti o kun fun eje,posii ati bebe lo.
Ti won si tun ba iwe idanimo awon omo ile-iwe sacred heart ti o wa ni oke-ilewo ni be,ti won ti pa,ni be na ni won ti ri awon obinrin meta ati omo kekere meta yo ni be.
Sugbon awon odo adugbo yii fi ofin si arawon ni owo lati tesiwaju lati sun ile na ni ina ati oko ayokele ti o wa ninu ogba na.
Agbenu so fun awon olopa ni ipinle ogun ogbeni Abimbola Oyeyemi,fi to wa leti pe owo siikun awon agbofinro ti te meji ninu awon odaran ti won fu ra si,ara binrin muibat ati aburo re ti won wa lati ilorin.

Comments