won yin ibon fun soro soro ori redio ti a mo si Akas Baba
Get link
Facebook
X
Pinterest
Email
Other Apps
Sorosoro ori redio ti wazobia fm ti port-harcourt ti oruko re je Anthony Akatapo ti ina gi je ren je Akas Baba,ni agbo wipe won yin ni bon si lese ti won si tun ji gbe lo ni owuro eni ti enikeni kosi da awon okunrin yii mo.
Eyin akoroyin imoran ti moni lati gba yin ni wipe ejeki oro ise yin dabi ti awon olopa, ibi ti e ba ti ri pe o lagbara ju fun yin lati lo e ma lo mo, ki olorun alaanu o se okunrin yi ni riri ni oo ( a o ni fi oju sunkun oniroyin tabi akoroyin kankan mo lagbara olorun AMIN)
Comments