ni ipinle borno iyen maiduguri ni ari gbo pe ado oloro kan tun dun ni arin ilu gege bi awon ako iroyin tii sahara fi ye wa(sahara reporters).
sugbon atun rigbo pe ko si ipalara tabi ohun ti ado oloro yii baje, won yun so di mi mo pe awon ajagun ti ile hausa iyen boko haram ni won tun fe gba ago awon oloogun ( major military base) ti won si tin yin ibon si ara won.

Comments