WON TI RI SORO SORO ORI REDIO TI WON JI GBE



Won ti ri akas baba ti awon ajini gbe,gbe lo ni ojo ketala osu keta ti odun ti a wa yi,ti won gbe lo ni waju ile re,iroyin fi to wa leti pe awon ti won ji gbe bere fun milionu mewa naira.

Comments