IMOREMI AJASORO


Olori Moremi wa lati Ile Ife ,i lu ti won ja ogun lorisirisi,pelu awon eya ti igbo ti o wa ni ile yoruba,opolopo awon omo ile ife ni a ti ko ni eru nigba na.
 moremi je akinkanju obinrin ti o rewa gidi gan,ti o fi gbogbo ohun ti o ni fi bo osa omi ESIMIRIN lati ko iya fun awon ara ilu ife.

lati inu imo ti bibeli eniyan bii mose,mariamu ati esiteri ni imoremi je,itan fi ye wa wipe awon eya ti igbo yi mu imoremi ni eru,sugbon ni ipase ewa re odi aya oba won ni ile na,ni eyin igba ti o ti mo asiri ogun won nigbana, o sa lo si ile ife lati lo tu asipi agbara yii fun awon jagun-jagun ti ile ife.
 leyin igbana ni o pada si odo oko e aro iyen oba ile-ife oba oranmiyan,ti oba si gba pada gege bi aya re,ni ipase lati mu ileri rte se fun odo ESIMIRIN ofi omo re kn soso fun omi yii iyen oluorogbo nitori ohun ti o bere fun niyen.

Comments