ile iwe alako beere ti ilu abuja tittun March 13, 2014 Get link Facebook X Pinterest Email Other Apps se eleyi wa fun mekunu tabi fun olowo? nigbati e ba pe eleyi ni ile eko alakobere bawo ni ile eko ti Yunifasiti se ma ri? ebawa be awon alagbara soro kiwon se fun awon mekunu. Comments dupson said… Olorun a so awa naa di eniyan patakI lawujo
Comments