IJA BE SILE NI ILE IWE BOWEN NI IWO.


Ija be si le ni iwe bowen ni ipinle osun ni ano ti a o si le so ni pato ohun ti o fa ija na,
awon omo ile iwe na so wipe ni pa ofin orisirisi ti won ma n fi si le ni ile iwe na ni o da ija na sile, ti awon omo ile iwe na si ba opolopo nkan je ni ile iwe na titi kan oko olori oluko ile iwe na.

Comments