gege bi iroyin titun ti a gbowipe, ikan lara awon ti o jawe olubori oscar ni ari pelu gbajugbaja olorin ti ilu somali ati canada ti a mo si Akewi Abdi Warsame eni ti a tun mo si k'naan, ni won tin jo jade po fun bii osu mefa si igba ta wa yi, ni osu keta yii ni a gbo wipe won ji jo lo si iforowero ti ori awounmaworan Kelly ati Michael sugbon awon eniyan ko ko bii ara sii won.
Comments