dahun si esun ti a fi kan e ki oye so ohun tiko ye fun awon ara ilu-jonathan so fun sanusi bee.

owo palaba oga ile ifowopamo ti ile wa sanusi ti se gi, nigbati olori orile ede wa fun lesi gbogbo ohun ti on so fun gbogbo eniyan orile ede, lori ohun ti on sele laarin won.

Comments

dupson said…
Sanusi lamido ti jehun yo ni CBN