awon omo ile iwe girama mewa ni won ku ninu ijanba oko ni ilu katsina.

ni bo ni orile ede wa n lo, iku o pa agba mo omode niku n pa ki olorun gbawa lowo iku ojiji.

Comments

dupson said…
Olorun a bawa dawo ibiduro