ARA BINRIN YI NA OMO EGBON RE,OMO ODUN MEWA DE ILE IWOSAN NITORIPE O TO LE.


sebi ni iwonba ni won ba omo wii,owo awon olopa ipinle eko ti te ara binrin ti o je omo odun meta di logbon ti o je asobode JOY AMADU, iroyin fi to wa leti pe nitoripe omo binrin kekere yi to si ori ibusun laimo ni o se na to fi di ti ile iwosan.

Comments