Ojo nla ti ilu-mo-on-ka ati agba oje osere fuji alaaji wasiu ayinde, ko le gbagbe ni ojo ti omo e oluwadamilola omogbolahan ti osese di amofin. ilu lekki,ni ipinle eko ni ayeye naa ti waye, bawon oloselu se wa nibe, bee na ni awon osere oni tiata o gbeyin naa, awon onisowo nla ati awon omo jayejaye eko naako gbeyin ni be.
Lara awon onitiata yoruba ti won dabira lojo naa ni dayo amusa adufe,fathia balogun,kemi afolabi ati kehinde bankole, bee ni gbajugbaja olorin igbalode olamide ti gbogbo eniyan npe ni 'badoo', ati osere onifuji alaaji sefiu alao adekunle, bee na ni oloselu seneto ganiyu solomon ati awon eniyan bebe lo.....
Comments