AWON ISELE NLA TI O SELE NI ODUN 2015

Image result for orioye sokunbi Image result for orioye sokunbiImage result for segun ogungbeImage result for pasuma
Odun 2015 ti lo, a ko tun ri mo laelae, odun nla, odun ti ko se e gbagbe boro, odun ti iku wole ti no mu AJIGIJAGA lo, odun ti o mu inspekito skede ki aye pe odigboose.erujeje odun ti ORIOYE SOKUNBI fi ile se aso bora,odun ti TAIWO ati KEHINDE ibeji ide ku. odun 2015 ti igbeyawo TOYIN AIMAKHU ati
oko e JOHNSON ADENIYI daru, odun nla ti DAYO AMUSA at YOMI FABIYI ni ijamba moto.
  Bi odun ti o koja yii se je odun ibanuje fawon osere kan, bee lo je odun ayo fawon mi-in. odun ti o koja yii ni ODUNLADE ODUNKOLA bimo okunrin, ti WUNMI AJIBOYE naa bimo obinrin fun SEGUN OGUNGBE, ti LALA si kawe gboye ni yunifasiti ife, odun ti o koja yii na ni PASUMA ko lo si ile tuntun.
 Eyin eyan wa eje ka sa ma dupe odun na bawa laye, ati ni aaye .......

Comments