AISAN JEJERE PA EGBON GBAJUGBAJA OLORIN AGBAYE CELINE DION.....


Leyin igba ti gbajugbaja olorin na padanu oko e ati manager eee si nu aisan jejere yii bakana ni egbon e, ki olorun ko yo wa ninu awon aisan buruku yi ti o gbaye kan bayii oo, e je ki a bo ju to oro ara wa ki aisan
buruku ma fi ara wa se ibugbe.

Comments